Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsita 2:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹsita wú Hegai lórí, inú rẹ̀ dùn sí i pupọ. Ó fún un ní nǹkan ìpara ati oúnjẹ kíákíá. Ó tún fún un ní àwọn ọmọbinrin meje ninu àwọn iranṣẹbinrin tí wọ́n wà ní ààfin. Ó fún Ẹsita ati àwọn iranṣẹbinrin rẹ̀ ní ibi tí ó dára jùlọ ní ibi tí àwọn ayaba ń gbé.

Ka pipe ipin Ẹsita 2

Wo Ẹsita 2:9 ni o tọ