Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsita 2:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní àkókò náà, nígbà tí Modekai jókòó ní ẹnu ọ̀nà ààfin, meji ninu àwọn ìwẹ̀fà ọba, tí wọn ń ṣọ́ ẹnu ọ̀nà: Bigitana ati Tereṣi, ń bínú sí ọba, wọ́n sì ń dìtẹ̀ láti pa Ahasu-erusi ọba.

Ka pipe ipin Ẹsita 2

Wo Ẹsita 2:21 ni o tọ