Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsita 1:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Àṣẹ ọba ni wọ́n tẹ̀lé nípa ọ̀rọ̀ ọtí mímu. Wọn kò fi ipá mú ẹnikẹ́ni, nítorí pé ọba ti pàṣẹ fún àwọn òṣìṣẹ́ ààfin pé ohun tí olukuluku bá fẹ́ ni kí wọn fi tẹ́ ẹ lọ́rùn.

Ka pipe ipin Ẹsita 1

Wo Ẹsita 1:8 ni o tọ