Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsira 9:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí mo gbọ́ bẹ́ẹ̀, mo fa aṣọ ati agbádá mi ya, láti fi ìbànújẹ́ mi hàn, mo sì fa irun orí ati irùngbọ̀n mi tu; mo sì jókòó pẹlu ìbànújẹ́.

Ka pipe ipin Ẹsira 9

Wo Ẹsira 9:3 ni o tọ