Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsira 8:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n fún àwọn aláṣẹ ati àwọn gomina tí ọba yàn fún àwọn ìgbèríko tí wọ́n wà ní òdìkejì odò ní ìwé àṣẹ tí ọba pa; àwọn aláṣẹ náà sì ṣe ìrànlọ́wọ́ fún wọn ati fún iṣẹ́ ilé Ọlọrun.

Ka pipe ipin Ẹsira 8

Wo Ẹsira 8:36 ni o tọ