Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsira 8:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo wọn fadaka, wúrà ati àwọn ohun èlò tí ọba, ati àwọn ìgbìmọ̀ rẹ̀, ati àwọn ẹmẹ̀wà rẹ̀ mú wá, ati èyí tí gbogbo àwọn ọmọ Israẹli tí wọ́n wà níbẹ̀ náà mú wá fún ìlò ilé Ọlọrun.

Ka pipe ipin Ẹsira 8

Wo Ẹsira 8:25 ni o tọ