Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsira 8:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Pẹlu ìrànlọ́wọ́ Ọlọrun, wọ́n fi Ṣerebaya, ọlọ́gbọ́n eniyan kan ranṣẹ sí wa. Ọmọ Israẹli ni, láti inú àwọn ọmọ Mahili, ninu ẹ̀yà Lefi: wọ́n fi ranṣẹ pẹlu àwọn ọmọ ati àwọn arakunrin rẹ̀. Gbogbo wọn jẹ́ mejidinlogun.

Ka pipe ipin Ẹsira 8

Wo Ẹsira 8:18 ni o tọ