Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsira 7:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọdún keje ìjọba Atasasesi, díẹ̀ ninu àwọn ọmọ Israẹli tí wọ́n ti ìgbèkùn dé: àwọn alufaa ati àwọn ọmọ Lefi, àwọn akọrin, àwọn aṣọ́nà ati àwọn iranṣẹ ninu Tẹmpili,

Ka pipe ipin Ẹsira 7

Wo Ẹsira 7:7 ni o tọ