Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsira 7:28 BIBELI MIMỌ (BM)

tí ó fi ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ hàn mí níwájú ọba, pẹlu àwọn ìgbìmọ̀ ati àwọn ẹmẹ̀wà rẹ̀ pataki pataki. Nítorí pé OLUWA Ọlọrun wà pẹlu mi, mo ṣe ọkàn gírí, mo kó àwọn aṣiwaju àwọn ọmọ Israẹli jọ, mo ní kí wọ́n bá mi kálọ.”

Ka pipe ipin Ẹsira 7

Wo Ẹsira 7:28 ni o tọ