Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsira 7:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹnikẹ́ni tí kò bá tẹríba fún òfin Ọlọrun rẹ ati àṣẹ ọba, pípa ni a óo pa á, tabi kí á wà á lọ kúrò ní ìlú, tabi kí á gba dúkìá rẹ̀, tabi kí á gbé e sọ sẹ́wọ̀n.”

Ka pipe ipin Ẹsira 7

Wo Ẹsira 7:26 ni o tọ