Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsira 6:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn alufaa ati àwọn ọmọ Lefi ya ara wọn sí mímọ́ lápapọ̀, fún ayẹyẹ náà. Wọ́n pa ọ̀dọ́ aguntan Àjọ Ìrékọjá fún àwọn tí wọ́n pada dé láti oko ẹrú, wọ́n pa fún àwọn alufaa ẹlẹgbẹ́ wọn, ati fún àwọn tìkara wọn.

Ka pipe ipin Ẹsira 6

Wo Ẹsira 6:20 ni o tọ