Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsira 6:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọgọrun-un ọ̀dọ́ akọ mààlúù, igba (200) àgbò, ati irinwo (400) ọ̀dọ́ aguntan ni wọ́n fi rú ẹbọ ìyàsímímọ́ náà. Wọ́n sì fi ewúrẹ́ kọ̀ọ̀kan rú ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀ fún ọ̀kọ̀ọ̀kan ninu ẹ̀yà Israẹli mejeejila.

Ka pipe ipin Ẹsira 6

Wo Ẹsira 6:17 ni o tọ