Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsira 5:17 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nítorí náà, kabiyesi, tí ó bá dára lójú rẹ, jẹ́ kí wọ́n lọ wo ìwé àkọsílẹ̀ ní Babiloni bí kìí bá ṣe nítòótọ́ ni Kirusi pàṣẹ pé kí wọ́n tún ilé Ọlọrun kọ́ ní Jerusalẹmu. Lẹ́yìn náà jẹ́ kí á mọ ohun tí o fẹ́ kí á ṣe nípa ọ̀rọ̀ yìí.”

Ka pipe ipin Ẹsira 5

Wo Ẹsira 5:17 ni o tọ