Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsira 4:2 BIBELI MIMỌ (BM)

wọ́n wá sọ́dọ̀ Serubabeli, ati sọ́dọ̀ àwọn baálé baálé, wọ́n wí fún wọn pé, “Ẹ jẹ́ kí á jọ kọ́ ọ nítorí ọ̀kan náà ni wá, Ọlọrun yín ni àwa náà ń sìn, a sì ti ń rúbọ sí i láti ìgbà ayé Esaradoni, ọba Asiria, tí ó mú wa wá síhìn-ín.”

Ka pipe ipin Ẹsira 4

Wo Ẹsira 4:2 ni o tọ