Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsira 3:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, wọ́n rú àwọn ẹbọ wọnyi: ẹbọ àtìgbà-dégbà, ẹbọ oṣù titun, gbogbo ẹbọ ọjọ́ àjọ̀dún tí a yà sọ́tọ̀ fún OLUWA, ati ti àwọn tí wọ́n bá fẹ́ rú ẹbọ àtinúwá sí OLUWA.

Ka pipe ipin Ẹsira 3

Wo Ẹsira 3:5 ni o tọ