Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsira 3:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n tẹ́ pẹpẹ náà sí ibi tí ó wà tẹ́lẹ̀, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé wọ́n ń bẹ̀rù àwọn eniyan ibẹ̀; wọ́n sì ń rú ẹbọ sísun sí OLUWA lórí rẹ̀ ní àràárọ̀ ati ní alaalẹ́.

Ka pipe ipin Ẹsira 3

Wo Ẹsira 3:3 ni o tọ