Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsira 3:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò sí ẹni tí ó lè mọ ìyàtọ̀ láàrin ariwo ẹkún ati ti ayọ̀ nítorí pé, gbogbo wọn ń kígbe sókè, tóbẹ́ẹ̀ tí àwọn eniyan sì gbọ́ igbe wọn ní ọ̀nà jíjìn réré.

Ka pipe ipin Ẹsira 3

Wo Ẹsira 3:13 ni o tọ