Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsira 3:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní oṣù keje tí àwọn ọmọ Israẹli ti pada sí ìlú wọn, gbogbo wọn péjọ sí Jerusalẹmu.

Ka pipe ipin Ẹsira 3

Wo Ẹsira 3:1 ni o tọ