Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsira 2:61 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn tí wọ́n jẹ́ ọmọ alufaa ninu wọn nìwọ̀nyí: àwọn ọmọ Habaya, àwọn ọmọ Hakosi, ati àwọn ọmọ Basilai (tí ó fẹ́ aya ninu ìdílé Basilai ará Gileadi, tí wọ́n sì ń fi orúkọ àna rẹ̀ pe àwọn ọmọ rẹ̀).

Ka pipe ipin Ẹsira 2

Wo Ẹsira 2:61 ni o tọ