Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsira 10:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí yóo fi di ọjọ́ kinni oṣù kinni, wọ́n ti parí ìwádìí lórí gbogbo àwọn tí wọ́n fẹ́ obinrin àjèjì.

Ka pipe ipin Ẹsira 10

Wo Ẹsira 10:17 ni o tọ