Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsira 1:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn olórí ninu ìdílé ẹ̀yà Juda ati ẹ̀yà Bẹnjamini, ati àwọn alufaa, ati àwọn ọmọ Lefi sì dìde, pẹlu àwọn tí Ọlọrun ti fi sí lọ́kàn láti tún ilé OLUWA tí ó wà ní Jerusalẹmu kọ́.

Ka pipe ipin Ẹsira 1

Wo Ẹsira 1:5 ni o tọ