Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsira 1:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Àpapọ̀ àwọn ohun èlò wúrà ati fadaka yìí jẹ́ ẹẹdẹgbaata ó lé irinwo (5,400). Ṣeṣibasari kó wọn lọ́wọ́ bí àwọn tí wọn kúrò ní oko ẹrú Babiloni ti ń bọ̀ wá sí Jerusalẹmu.

Ka pipe ipin Ẹsira 1

Wo Ẹsira 1:11 ni o tọ