Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsira 1:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọdún kinni ìjọba Kirusi, ọba Pasia, kí àsọtẹ́lẹ̀ láti ẹnu wolii Jeremaya lè ṣẹ, OLUWA fi sí Kirusi ọba lọ́kàn láti kéde yíká gbogbo ìjọba rẹ̀ ati láti ṣe àkọsílẹ̀ rẹ̀ pé:

Ka pipe ipin Ẹsira 1

Wo Ẹsira 1:1 ni o tọ