Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkún Jeremaya 3:9-11 BIBELI MIMỌ (BM)

9. Ó to òkúta gbígbẹ́ dí ọ̀nà mi,ó mú kí ọ̀nà mí wọ́.

10. Ó ba dè mí bí ẹranko ìjàkùmọ̀,ó lúgọ bíi kinniun,

11. Ó wọ́ mi kúrò lójú ọ̀nà mi,ó fà mí ya pẹ́rẹpẹ̀rẹ,ó sì ti sọ mí di alailẹnikan.

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremaya 3