Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkún Jeremaya 3:62-64 BIBELI MIMỌ (BM)

62. Gbogbo ọ̀rọ̀ ati èrò àwọn ọ̀tá mi sí mi:ibi ni lojoojumọ.

63. Kíyèsí i, wọn ìbáà jókòó,wọn ìbáà dìde dúró,èmi ni wọ́n máa fi ń kọrin.

64. “O óo san ẹ̀san fún wọn, OLUWA,gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ ọwọ́ wọn.

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremaya 3