Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkún Jeremaya 3:3-6 BIBELI MIMỌ (BM)

3. Dájúdájú, ó ti dojú kọ mí,ó sì bá mi jà léraléra tọ̀sán-tòru.

4. Ó ti jẹ́ kí n rù kan egungun,ó sì ti fọ́ egungun mi.

5. Ó dótì mí,ó fi ìbànújẹ́ ati ìṣẹ́ yí mi káàkiri.

6. Ó fi mí sinu òkùnkùnbí òkú tí ó ti kú láti ọjọ́ pípẹ́.

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremaya 3