Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkún Jeremaya 3:16-18 BIBELI MIMỌ (BM)

16. Ó fẹnu mi gbolẹ̀,títí yangí fi ká mi léyín;ó gún mi mọ́lẹ̀ ninu eruku

17. Ọkàn mi kò ní alaafia,mo ti gbàgbé ohun tí ń jẹ́ ayọ̀.

18. Nítorí náà, mo wí pé,“Ògo mi ti tán,ati gbogbo ohun tí mò ń retí lọ́dọ̀ OLUWA.”

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremaya 3