Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkún Jeremaya 2:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn àgbààgbà Sioni jókòó lórí ilẹ̀, wọ́n dákẹ́ rọ́rọ́,wọ́n ku eruku sórí,wọ́n sì wọ aṣọ ọ̀fọ̀.Àwọn ọmọbinrin Jerusalẹmu doríkodò.

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremaya 2

Wo Ẹkún Jeremaya 2:10 ni o tọ