Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkún Jeremaya 1:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Juda ti lọ sí ìgbèkùn,wọ́n sì ń fi tipátipá mú un sìn.Nisinsinyii, ó ń gbéààrin àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn,kò sì ní ibi ìsinmi.Ọwọ́ àwọn tí wọn ń lépa rẹ̀ ti tẹ̀ ẹ́,ninu ìdààmú rẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremaya 1

Wo Ẹkún Jeremaya 1:3 ni o tọ