“Ranti gbogbo ìwà ibi wọn,kí o sì jẹ wọ́n níyà;bí o ti jẹ mí níyà,nítorí gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ mi.Ìrora mi pọ̀ ọkàn mi sì rẹ̀wẹ̀sì.”