Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkún Jeremaya 1:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ wò ó bí ìlú tí ó kún fún eniyan tẹ́lẹ̀ ti di ahoro,tí ó wá dàbí opó!Ìlú tí ó tóbi láàrin àwọn orílẹ̀-èdè tẹ́lẹ̀!Tí ó sì dàbí ọmọ ọba obinrinláàrin àwọn ìlú yòókù.Ó ti wá di ẹni àmúsìn.

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremaya 1

Wo Ẹkún Jeremaya 1:1 ni o tọ