Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 9:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó di ọjọ́ keji OLUWA ṣe bí ó ti wí; gbogbo àwọn ẹran ọ̀sìn àwọn ará Ijipti kú, ṣugbọn ẹyọ kan ṣoṣo kò kú ninu ẹran ọ̀sìn àwọn ọmọ Israẹli.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 9

Wo Ẹkisodu 9:6 ni o tọ