Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 9:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Farao bá ranṣẹ pe Mose ati Aaroni, ó sọ fún wọn pé, “Mo ti dẹ́ṣẹ̀ nisinsinyii; OLUWA jàre, èmi ati àwọn eniyan mi ni a jẹ̀bi.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 9

Wo Ẹkisodu 9:27 ni o tọ