Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 9:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, yára ranṣẹ lọ kó gbogbo àwọn ẹran rẹ tí wọ́n wà ninu pápá síbi ìpamọ́, nítorí pé yìnyín yóo rọ̀ sórí eniyan ati ẹranko tí ó bá wà ní pápá, tí wọn kò bá kó wọlé, gbogbo wọn ni yóo sì kú.”

Ka pipe ipin Ẹkisodu 9

Wo Ẹkisodu 9:19 ni o tọ