Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 9:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun tún sọ fún Mose pé kí ó wọlé tọ Farao lọ, kí ó sì sọ fún un pé kí ó gbọ́ ohun tí òun OLUWA Ọlọrun àwọn Heberu wí, kí ó jẹ́ kí àwọn eniyan òun lọ sìn òun.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 9

Wo Ẹkisodu 9:1 ni o tọ