Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 8:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Mose dá Farao lóhùn pé, “Sọ ìgbà tí o fẹ́ kí n gbadura fún ìwọ ati àwọn ẹmẹ̀wà rẹ, ati àwọn eniyan rẹ, kí Ọlọrun lè run gbogbo àwọn ọ̀pọ̀lọ́ tí wọ́n wà lọ́dọ̀ yín, ati ninu ilé yín; kí ó sì jẹ́ pé kìkì odò Naili nìkan ni ọ̀pọ̀lọ́ yóo kù sí.”

Ka pipe ipin Ẹkisodu 8

Wo Ẹkisodu 8:9 ni o tọ