Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 8:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Mose dá a lóhùn pé, “Kò ní tọ̀nà bí a bá ṣe bẹ́ẹ̀; nítorí pé àwọn nǹkan mìíràn lè wà ninu ohun tí a óo fi rúbọ sí OLUWA Ọlọrun wa tí ó lè jẹ́ ìríra fún àwọn ará Ijipti. Bí a bá fi ohunkohun rúbọ tí ó jẹ́ ìríra lójú àwọn ará Ijipti, ṣé wọn kò ní sọ wá ní òkúta pa?

Ka pipe ipin Ẹkisodu 8

Wo Ẹkisodu 8:26 ni o tọ