Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 8:24 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ṣe bẹ́ẹ̀; ọ̀wọ́ eṣinṣin wọ inú ilé Farao ati ti àwọn ẹmẹ̀wà rẹ̀ ati gbogbo ilẹ̀ àwọn ará Ijipti. Eṣinṣin sì ba ilẹ̀ náà jẹ́.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 8

Wo Ẹkisodu 8:24 ni o tọ