Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 8:20 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA bá tún sọ fún Mose pé, “Dìde ní òwúrọ̀ kutukutu, kí o lọ dúró de ọba Farao bí ó bá ti ń jáde lọ sétí odò, wí fún un pé, kí ó gbọ́ ohun tí èmi OLUWA wí, pé kí ó jẹ́ kí àwọn eniyan mi lọ sìn mí.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 8

Wo Ẹkisodu 8:20 ni o tọ