Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 8:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Farao rí i pé gbogbo ọ̀pọ̀lọ́ náà kú tán, ọkàn rẹ̀ tún le, kò sì ṣe ohun tí Mose ati Aaroni wí mọ́, gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti sọ tẹ́lẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 8

Wo Ẹkisodu 8:15 ni o tọ