Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 7:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Mose ati Aaroni ṣe gẹ́gẹ́ bí àṣẹ OLUWA lójú Farao ati lójú gbogbo àwọn ẹmẹ̀wà rẹ̀. Aaroni gbé ọ̀pá rẹ̀ sókè ó sì fi lu omi tí ó wà ninu odò Naili, gbogbo omi tí ó wà ninu odò náà sì di ẹ̀jẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 7

Wo Ẹkisodu 7:20 ni o tọ