Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 7:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Tọ Farao lọ ní òwúrọ̀, bí ó bá ti ń jáde lọ sí etídò, kí o dúró dè é ní etí bèbè odò, kí o sì mú ọ̀pá tí ó di ejò lọ́wọ́.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 7

Wo Ẹkisodu 7:15 ni o tọ