Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 6:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Aaroni fẹ́ Eliṣeba ọmọbinrin Aminadabu tíí ṣe arabinrin Naṣoni. Àwọn ọmọ tí ó bí fún un nìwọ̀nyí: Nadabu, Abihu, Eleasari, ati Itamari.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 6

Wo Ẹkisodu 6:23 ni o tọ