Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 6:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Lefi bí ọmọ mẹta: Geriṣoni, Kohati ati Merari; àwọn ni olórí àwọn ìdílé ẹ̀yà Lefi. Ọdún mẹtadinlogoje (137) ni Lefi gbé láyé.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 6

Wo Ẹkisodu 6:16 ni o tọ