Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 6:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn OLUWA sọ fún Mose pé, “O óo rí ohun tí n óo ṣe sí ọba Farao; ó fẹ́, ó kọ̀, yóo jẹ́ kí àwọn eniyan mi lọ, fúnra rẹ̀ ni yóo sì fi ipá tì wọ́n jáde.”

Ka pipe ipin Ẹkisodu 6

Wo Ẹkisodu 6:1 ni o tọ