Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 5:21 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ọlọrun ni yóo dájọ́ fún yín, ẹ̀yin tí ẹ sọ wá di ẹni ìríra níwájú Farao ati àwọn iranṣẹ rẹ̀, ẹ sì ti yọ idà lé wọn lọ́wọ́ kí wọ́n fi pa wá.”

Ka pipe ipin Ẹkisodu 5

Wo Ẹkisodu 5:21 ni o tọ