Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 5:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn tí wọ́n jẹ́ olórí láàrin àwọn ọmọ Israẹli rí i pé àwọn wà ninu ewu, nígbà tí wọ́n gbọ́ pé iye bíríkì tí àwọn ń mọ lojumọ kò gbọdọ̀ dín rárá.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 5

Wo Ẹkisodu 5:19 ni o tọ