Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 5:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn akóniṣiṣẹ́ Farao bẹ̀rẹ̀ sí na àwọn tí wọ́n fi ṣe olórí láàrin àwọn ọmọ Israẹli. Wọn á máa bi wọ́n pé “Kí ló dé tí bíríkì tí ẹ mọ lónìí kò fi tó iye tí ó yẹ kí ẹ mọ?”

Ka pipe ipin Ẹkisodu 5

Wo Ẹkisodu 5:14 ni o tọ