Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 5:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn tí wọn ń kó àwọn ọmọ Israẹli ṣiṣẹ́ bá jáde tọ̀ wọ́n lọ, wọ́n sọ fún wọn pé, “Ẹ gbọ́ bí Farao ti wí; ó ní òun kò ní fún yín ní koríko mọ́.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 5

Wo Ẹkisodu 5:10 ni o tọ