Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 39:42-43 BIBELI MIMỌ (BM)

42. Gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti pàṣẹ fún Mose, ni àwọn eniyan Israẹli ṣe gbogbo iṣẹ́ náà.

43. Mose wo gbogbo iṣẹ́ náà, ó rí i pé wọ́n ṣe é gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti pa á láṣẹ, Mose sì súre fún wọn.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 39